ORISI IGBEYAWO MARUN
1. Igbeyawo
Kristiani
2. Igbeyawo
Alarede
3. Igbeyawo
Awuruju
4. Igbeyawo
Alalumokoroyi
5. Igbeyawo
Alalubaagi
ORISI IYAWO
MEJE
1. Iyawo Saara
(Alawin)
2. Iyawo Awosin
3. Iyawo Alagbabo
4. Iyawo Alabodo
5. Iyawo Alarodan
6. Iyawo Alarobo
7. Iyawo Alarede
ORISI OKO MEJE
1. Oko Besue
2. Oko Alakatakiti
3. Oko gbogbo
Omoge (Afurugbin)
4. Oko ori Irin
5. Oko Alabosin
6. Oko Alajopin
7. Oko Alarede
ASIRI OHUN TO MAA
NFA ASIFE OKO TABI ASIYAN AYA
1. Ai ni imo nipa
igbeyawo.
2. Oju dara- dara
ati ewa- 1 Sam 16:7.
3. Ikanju ati
igbonara.
4. Itara ati Ebun.
5. Dukia ati ipo.
6. Imoran- odi-
Onidajo 21:21.
7. Imisi Obi- Gen
21:20-21.
8. Iran
ati Asotele woli.
9. Ala ati Igbohun.
10. Awokose ati
Afarawe.
11. Igberaga ati
Ijora-eniloju.
12. Eleya- meya
13. Adura Iborisa-
Esekiel 14:3, Num 22:12; 18-19.
14. Ifekufe ati
Ipongbe eran ara (Ife
gbigbona) Onidajo 14:1-3, 2 Sam 11:1-5, 27.
15. Iwa awon
Alaigbagbo- Gen 12:14-15, 17; 34:1-4, 26.
16. Ibanikedun ati
oju aanu.
17. Egun Ajogunba
ati ogun idile
18. Ise Asepa
okunkun.
EWU ASIYAN NINU
IGBEYAWO
Bi o ba siyan …
1. O lee di oku
laaye.
2. O lee padanu iran
ati kadara daradara re.
3. Ifokanbale ati
alaafia yio jinna si o.
4. O lee di edun
arinle ati akurete ninu irin ajo igbagbo.
5. Aasiki ati ogo
abawaye re lee sonu.
6. O lee yori si
iku aitojo fun o.
7. O lee di ero
orun apaadi lopin aye re.
BI O KO BA FE
SIYAN
1. Di atunbi ninu
Kristi.
2. Lepa fun imo
lori oro igbeyawo kristiani.
- Nipase eko
Bibeli (Bible study, Sunday school, marriage seminar)
- Nipa wiwa inu
iwe mimo ati sise asaro ninu oro Olorun.
- Nipa Ibeere ati
gbigba imoran lowo awon adari tooto.
3. Mase fi aaye
gba orisa tabi ifekufe kankan
ninu okan re.
- Iru eni bayi lo
wumi lati fe
- Iru eniyan bayi
ni mi o lee fe
4. Yonda ife okan re patapata fun
Olorun, ki o si fi aaye gba lati yan fun o.
- Oun lo da o, o
si mo ojo ola re.
- Oun lo mo eni ti
o ye fun ojo- ola re.
- Ife Olorun fun o
ko lee ni abamo lehinwa ola.
5. Ni suuru fun
Olorun lati se ise re ni asepe lori eto igbeyawo re.
6. Kun fun awe ati
adura
- Lati maa beere
fun imuse ife
Olorun lai ni idena.
- Lati maa beere
fun ore- ofe ati oju rere Olorun.
- Lati ni isegun
lori arekereke esu, egun idile, ogun ajogunba, takute ese abbl.
7. Maa mura ara re
sile fun asepe ojo iwaju.
- Awon iwa abinibi
tabi ise eran ara wo ni o gbodo parun?
- Lepa lati mo ete
Olorun fun iwasaye re, ki o si maa sakitiyan lati muu se.
- Maa lepa lati mo
ife Olorun ati
lati je oluse Oro Re.
8. Ni oluso
aguntan.
- Oun ni yio maa
fi adura ran o lowo.
- Oun ni yio maa
se so lori aye re.
- Oun ni yio maa
to o sona.
- Oun ni yio maa
fun o ni imisi ati irusoke.
No comments:
Post a Comment