Monday, 3 November 2014

ISUBU AWON IRANSE OLORUN 2 Sam 1:27



ISUBU AWON IRANSE OLORUN 2 Sam 1:27.
Bi a ba n soro nipa isubu awon iranse- Olorun, a n so nipa isubu awon alagbara ati akoni igbagbo lati inu ogo sinu ofo. O tumo si wipe ki eni to ti figba kan gbona- janjan ninu ife Olorun wa pehinda, ko palana-da, ki o si kehin si Olorun.

Nigba ti iranse- Olorun ba ya kuro ni oju ona tooro, ti o si bo si oju ona gbooro; nigba ti iranse Olorun ba jade kuro ninu ife Olorun to si tipa se bee gba ofa nipa tara tabi nipa ti emi, iru eni bee ti subu.  

AWON ASIRI PATAKI TI A GBODO MO NIPA ISUBU IRANSE-OLORUN

1. Opolopo awon akoni ati alagbara igbagbo to subu loni lo ti figba kan gbona giri- giri fun Olorun, won ti se opo ise iyanu, won si ti jere oke aimoye okan si ijoba- orun- Ise Aposteli 1:15-20.

2. Opolopo won lo bere dara- dara pelu Kristi, won n lepa iwa mimo, won si ni ipinnu lati pari ere ije won daradara sugbon takute esu mu won, won si subu-

3. Opolopo awon akoni wonyi ni ko fura wipe satani atawon omo ogun orun apaadi n kora jo po, won si n lepa isubu won lonakona pelu ibinu ati irunu nla- 1 Peter 5:8-9.

4. Ota kan soso naa to gbe awon yen subu lo n lepa lati fa awa naa lule, o si n foju sona lati saseyori lori wa gege bi o se se lori awon wonyen.

Idi niyen ti Bibeli fi kilo fun wa pe eni to baro wipe oun duro ki o kiyesara- 1 Kor 10:12.

5. Ko si akoni tabi alagbara kan ti ko lee subu ayafi enikeni to ba gboran si ilana Bibeli to n kiyesara, to si n figba gbogbo wa oju Olorun ati ore ofe Re ninu adura adagba ikoko ati iranlowo adura awon eniyan Olorun- 2 Tess 3:1-2.
6. Awon to subu ko rokan wipe awon lee subu beyen naa, o ti sele tan ki oju opolopo to wale- Matt 26:69-75.

7. Satani ko so ireti nu lori enikeni lai bikita bi o ti wu ki iru eni bee ti pe to, jinle to tabi lagbara to ninu igbagbo, niwon igba ti onitoun ba si n gbe inu ago- ara.

8. Isubu iranse Olorun kii se ohun ti a fi n sesin eleya tabi takuroso laarin ara wa pelu enu egan, ibanuje nla ni fun orun ati ajalu buburu fun ijo Kristi- 2 Sam 1:17-27.

9. Awon ojulowo omo Olorun to ni oye eko Bibeli ko ni kede isubu iranse Olorun tabi fi won se eleya bikose pe ki won fi iwariri ati okan irele ran won lowo lonakona lati tete mu won bo sipo- Gal 6:1-3.

10. A gbodo fara bale keko, ki a si kogbon lara apeere awon to subu ki awa naa ma baa se iru asise ti won se- 1 Kor 10:6-12.

11. Olorun mo bi o se maa n fi owo anu ati ore ofe gbe awon iranse Re to ba subu dide- Psalmu 37:23-24, Psalmu 34: 18-19.

12. Ni opolopo igba, eni to subu ti ronupiwada, o si ti tun ona re se niwaju Olorun atawon to se asise si (restitution) sugbon awon alaimokan a si maa fi oju elese wo iru iranse Olorun bee.


OKUNFA ISUBU AWON IRANSE OLORUN- 1 Kor 10:6-12.

1. Fifi ife isaaju sile- Ifihan 2:1-5.

v     Ife isaaju ni igbona okan ati itara wa fun Olorun ati Oro iwa mimo Re lasiko ti a koko ni iriri ati idaniloju igbala eyi to mu ki a maa fi gbogbo ipa ati okan wa lepa lati mo ati lati maa se ohun ti yio mu inu Olorun dun nigba naa.
v     Fifi ife isaaju sile tumo si gbigba emi irewesi ati iyemeji laaye lati ba igbagbo wa ninu awon ileri Olorun ati Oro Re je-

Boya nitori…
-          Ogun isoro tabi iponju olojo pipe- Onidajo 6:11-13.
-          Ireti pipe-
-          Oro egan tabi ifiniseleya lati enu awon alaigbagbo.
-          Ise rere awon eniyan buburu nigba ti awon olododo n jiya- Mal 3:14-15, Psalmu 73:2-14.
-          Oro odi ati imisi irewesi nipase awon eleko eke- Gal 5:7-9.
Sakiyesi Gal 3:1-4.
                               
v     Fifi ife isaaju sile tumo si fifi ise pupo “nihin ati lohun” dira eni lowo (ai ri aaye lati sabojuto okan tiwa) - 1 Oba 20:35-43.  O tumo si sise aniyan ati laala nitori ohun pupo lai fi aaye sile fun ilepa lati mo ati lati se ife Olorun- Lk 10:38-42.

Ami awon nkan wonyi saba maa n fara han nigba ti…
-          Nigba ti diduro niwaju awon eniyan lati maa se ise iranse ba ti n di lemolemo to bee ti a ko fi ri aaye lati kunle niwaju Olorun fun ibasepo mimo pelu Re mo.
-          Nigba ti adura ita gba-n- gba laarin opo ero ba ti n di gbogbo igba de bi wipe ko si aaye fun wa lati wa oju Olorun ninu adura adagba nikoko mo.
-          Nigba ti bibojuto awon ara ita ko ba fun wa laaye lati bojuto idile wa mo.
-          Nigba ti ttitoju awon miran ko ba fi aaye gba wa lati toju ago ara wa mo.
-          Nigba ti a ba ti n gba awe olojo gbooro lai wa akoko fun sisasaro ninu oro Olorun ati adura adagba.
-          Fifi gbogbo agbara wa se ise iranse fun awon eniyan nigba gbogbo lai si eni kankan to n se ise iranse fun okan ti wa (Seminars, Bible studies, Refresher course, conference, etc).
-          Fifi ife isaaju sile tumo si riri ara eni gege bi eni to ti kun oju osuwon igbagbo, eni ti o ti gbon tan ti ko nilo abojuto adari tabi se isiro fun enikeni-
-          Kikun fun emi igberaga ati ijora eni loju nitori ifarahan awon ebun emi- Hosea 13:1.
-          Idaniloju ati igbekele ninu ara eni (self confidence), sisogo ati si sinmi le awon aseyori ati ibukun ise iranse asiko yi- Fil 3:12-14.
-          Kikegan ati fifi oju alaimoose wo awon akegbe tabi asiwaju ti ko ni ebun tabi ise- iranse nla bii tiwa.
-          Siso awon oro iponra- eni- le ati isera- eni-logo niwaju awon eniyan gege bi eni nla pataki kan- Ise Aposteli 12:21-24.
-          Lilepa fun awon oruko ati oye- nla pelu ipo- ola lawujo. Won a wipe opon ti sun, level ti change – Matt. 23:5-12
-          Sise afojudi si oro-Olorun, kikegan ikilo tabi ibawi awon adari rere, ati kikorira awon to n bani so otito – Gal 4:15-16

2. Fifi ipa eran-ara se ise ti emi tabi fi fi ohun ija ti ara jagun emi – Gal 3:3

Nigba ti a ba ti fi ife wa isaaju sile, ti a ko si ni ibasepo timotimo pelu Olorun mo, iwonyi ni awon ami ti yio bere si nii fara han:
-          Fifi ete ati ogbon-ori dipo itoni Emi-Mimo.
-          Fifi owo ati awon eniyan nla-nla ti a mo ri dipo ifihan agbara Emi-Mimo.
-          Lilepa fun isowo ati karakata to lee mu owo wole dipo ise ijere-okan ati itankale ihinrere.
-          Siso oro ihale, egun ati ikoni-laya-je lati fi awon omo-ijo sinu ipaya lati ribi jega-bale won lori dipo fifara bale ko won ni eko oro Olorun, bibawon wi ninu ife ati fifi okan won le Olorun lowo ninu adura ikoko.
-          Si sare tele awon olowo, olola atawon eni nla aye lati wa iranlowo won lori isoro tabi ipenija ti o dojuko wa dipo wiwa oju Olorun fun ona-abayo.
-          Sisoro nipa eto oselu atawon oro to n lo lawujo lori pepe dipo wiwaasu ogidi oro Olorun.
-          Wiwa ori ero ayelujara fun akori ati koko inu iwaasu dipo wiwa inu Bibeli.
-          Sise awokose ati afarawe awon woli ati iranse-Olorun nla (big man of God) dipo Kristi Jesu – Heb. 12.2.

3. Emi Aikiyesara – Matt. 7:3-5
Ai kiyesara lo maa n mu ki a bojuto ogba-ajara elomiran nigba ti ogba ajara ti wa n baje lo. Orin  Sol. 1:6.

* Alaafia ati ileera ninu ago-ara wa – Fil 2:25-30

Ago-ara ni oko ti Emi-Mimo n lo lati fi sise. Bi ago-ara naa ba si ti baje nitori ai ri itoju, Emi Mimo a fo jade, ise-iranse a si pari. Bi ise-iranse ba si ti pari, awon t o n tele wa a sa pada, won a tun wa elomiran lo.

* Eto igbeyawo ati idile wa – 1 Timo. 3:8.

- Iyawo wa ni ojuse akoko ti a gbodo koko bojuto saaju enikeni ninu ise-iranse. A gbodo sa gbogbo ipa wa lati koo ati lati muu dagba ninu emi, ki o lee wa pelu wa nigba gbogbo gege bi:-
1. Alabakegbepo
2. Alabaro ati olubanidamoran
3. Alajogbadurapo
4. Ore kori-kosun

Bi a ba ti kuro lori iyawo wa, ogiri idile a lanu, ala-n-gba ota a si wole lati wa furugbin buburu tabi lati wa ja wa lole ogo.

Eleyi si lo maa n fa oniruuru isele buburu fun iranse-Olorun:
1. Ai se deede okan pelu iyawo je anfani kan pataki ti satani maa n lo lati ta ofa agbere sinu aye iranse-Olorun ati lati faaye gba awon ajeji-obinrin.
2. Ai si ni isokan pelu iyawo maa n fi aaye sile fun ofa-okunkun (emi aisan, iku tabi emi isiwahu) lati ba iranse-Olorun, iyawo tabi awon omo won.
3. Ai ni ifowosowopo ati inu kan pelu iyawo wa maa n yori si ogun adaja eyi to tete maa n fa isubu fun iranse- Olorun

* Ibasepo pelu awon obinrin- 1 Tess 5:22, 2 Kor 4:1-2.
- Fifaramo ati sise wole- wode pelu obinrin ti kii se iyawo wa lona to lee mu ifura si dani.
- Sise ibarinpo tabi ajosepo pelu obinrin miran lona ti o lee mu ki iyawo wa ma lee gberi wa je.
- Di danikan se igbani- nimoran tabi adura itusile fun obinrin ni koro tabi nibi okunkun.
- Sise iranlowo pataki fun tabi gbigba nkan lowo obinrin laije ki iyawo wa mo sii.

* Fifi asiri aileera tabi asise wa pamo fun awon to lee ran wa lowo- Psalmu 38:17-19.

Iyawo/ oko ati adari wa ninu ise- iranse je awon ti a ko gbodo ti owo to n dun wa boso fun- Jms 5:16.   

ASIYAN NINU IGBEYAWO- Gen 20:1-3



ORISI IGBEYAWO MARUN
1. Igbeyawo Kristiani
2. Igbeyawo Alarede
3. Igbeyawo Awuruju
4. Igbeyawo Alalumokoroyi
5. Igbeyawo Alalubaagi

ORISI IYAWO MEJE
1. Iyawo Saara (Alawin)
2. Iyawo Awosin
3. Iyawo Alagbabo
4. Iyawo Alabodo
5. Iyawo Alarodan
6. Iyawo Alarobo
7. Iyawo Alarede

ORISI OKO MEJE
1. Oko Besue
2. Oko Alakatakiti
3. Oko gbogbo Omoge (Afurugbin)
4.  Oko ori Irin
5. Oko Alabosin
6. Oko Alajopin
7. Oko Alarede

ASIRI OHUN TO MAA NFA ASIFE OKO TABI ASIYAN AYA

1. Ai ni imo nipa igbeyawo.
2. Oju dara- dara ati ewa- 1 Sam 16:7.
3. Ikanju ati igbonara.
4. Itara ati Ebun.
5. Dukia ati ipo.
6. Imoran- odi- Onidajo 21:21.
7. Imisi Obi- Gen 21:20-21.
8. Iran ati Asotele woli.
9. Ala ati Igbohun.
10. Awokose ati Afarawe.
11. Igberaga ati Ijora-eniloju.
12. Eleya- meya
13. Adura Iborisa- Esekiel 14:3, Num 22:12; 18-19.
14. Ifekufe ati Ipongbe eran ara (Ife gbigbona) Onidajo 14:1-3, 2 Sam 11:1-5, 27.
15. Iwa awon Alaigbagbo- Gen 12:14-15, 17; 34:1-4, 26.
16. Ibanikedun ati oju aanu.
17. Egun Ajogunba ati ogun idile
18. Ise Asepa okunkun.

EWU ASIYAN NINU IGBEYAWO

Bi o ba siyan …
1. O lee di oku laaye.
2. O lee padanu iran ati kadara daradara re.
3. Ifokanbale ati alaafia yio jinna si o.
4. O lee di edun arinle ati akurete ninu irin ajo igbagbo.
5. Aasiki ati ogo abawaye re lee sonu.
6. O lee yori si iku aitojo fun o.
7. O lee di ero orun apaadi lopin aye re.

BI O KO BA FE SIYAN
1. Di atunbi ninu Kristi.

2. Lepa fun imo lori oro igbeyawo kristiani.
- Nipase eko Bibeli (Bible study, Sunday school, marriage seminar)
- Nipa wiwa inu iwe mimo ati sise asaro ninu oro Olorun.
- Nipa Ibeere ati gbigba imoran lowo awon adari tooto.

3. Mase fi aaye gba orisa tabi ifekufe kankan ninu okan re.
- Iru eni bayi lo wumi lati fe
- Iru eniyan bayi ni mi o lee fe

4. Yonda ife okan re patapata fun Olorun, ki o si fi aaye gba lati yan fun o.
- Oun lo da o, o si mo ojo ola re.
- Oun lo mo eni ti o ye fun ojo- ola re.
- Ife Olorun fun o ko lee ni abamo lehinwa ola.

5. Ni suuru fun Olorun lati se ise re ni asepe lori eto igbeyawo re.

6. Kun fun awe ati adura
- Lati maa beere fun imuse ife Olorun lai ni idena.
- Lati maa beere fun ore- ofe ati oju rere Olorun.
- Lati ni isegun lori arekereke esu, egun idile, ogun ajogunba, takute ese abbl.

7. Maa mura ara re sile fun asepe ojo iwaju.
- Awon iwa abinibi tabi ise eran ara wo ni o gbodo parun?
- Lepa lati mo ete Olorun fun iwasaye re, ki o si maa sakitiyan lati muu se.
- Maa lepa lati mo ife Olorun ati lati je oluse Oro Re.

8. Ni oluso aguntan.
- Oun ni yio maa fi adura ran o lowo.
- Oun ni yio maa se so lori aye re.
- Oun ni yio maa to o sona.
- Oun ni yio maa fun o ni imisi ati irusoke.

SAWARI EBUN EMI RE KI O SI SAMULO RE LEKUN RERE Rom 12:3-8, 1 Peter 4:10-11.



O se ni laanu lode oni lati rii wipe oke aimoye kristaini ati pupo ninu awon to n pe ra won ni iranse-Olorun ni ko loye nipa awon ebun Emi tabi bi a ti se lee samulo won fun ise-iranse to leso- 1 Kor 12:1.

Oto ni ipe, oto si ni ebun-Emi. Awon ebun-emi ni irin-ise ti a fi fun awon eni ipe lati lee se ise- iranse won lona ti yoo laseyori – 1 Kor 12:7. Ko si kristaini kan tabi iranse-Olorun kan ti ko ni ebun – Emi tire, eyi ti a fi fun lati oke wa – 1 Kor 12:11.

Lotito, Olorun lo n fun awon eni –ipe ni oniruuru ebun- emi, sugbon ojuse onikaluku ni lati sawari ati lati samulo awon ebun naa lekunrere – 1 Tim 4:14-16, 2 Tim 1:6. Bi eniyan ba ni ipe- Olorun nitooto, sugbon bi ko ba mo bi a ti n sawari ebun- emi ati bi a ti n samulo won, onitoun a maa jiya ninu ise-iranse bi eni ti ko ni ipe ni- Psalm 49:20.

KINI AWON EBUN- EMI?
Awon ebun-emi ni akanse ipe tabi agbara ti a yonda fun kristaini tabi iranse- Olorun kookan latoke wa lati se awon akanse ise- isin tabi ise- iranse fun iranlowo awon elomiran, igbero ijo Olorun, titankale ihinrere ati lati mu ogo ba oruko Olorun nibi gbogbo.   

IDI TI A SE GBODO SAWARI AWON EBUN- EMI KI A SI SAMULO WON
1. Ki a ma baa je ope nipa awon ohun tie mi – 1 Kor 12:11.
2. Ki a lee mu ete ati erongba Olorun fun iwasaye wa se-
3. Ki a lee je ohun- elo si ola nigba ti ise-iranse wa ba mu ere nla wa fun Olorun-
4. Ki a lee mu ife Olorun se ninu aye, ki imole ogo Re lee kun gbogbo aye bi omi ti n kun inu    okun-
5. Ki a lee gba awon eniyan kuro ninu agbara satani si Olorun, ki won ki o lee di eda- titun ninu Kristi-

IPELE META TI A PIN AWON EBUN EMI SI- 1 Kor 12:4-7.

AWON EBUN EMI – Awon wonyi ni awon ebun meseesan ti a daruko ninu iwe 1 Kor 12:8-10. Ipele meta ni a pin awon ebun meseesan wonyi si gege bi a ti salaye won nisale yi:

1. AWON EBUN IMISI
- Isotele-
- Oniruuru- ede-
- Itumo- ede-

2. AWON EBUN AGBARA
- Igbagbo-
- Ebun Imularada-
- Ise Iyanu ise-
 3. AWON EBUN IFIHAN
- Oro Ogbon
- Oro Imo
- Imo Emi-yato.

ü      Awon ebun meseesan wonyi ni a n pe ni awon ebun- emi nitori pe lati owo Emi Mimo ni a ti n yonda won fun wa – 1 Kor 12:4, 8-11. Awon ebun wonyi si wa fun gbogbo kristiani ti o ba ti gba Emi Mimo lati fi jere fun Kristi – 1 Kor 12:7, 11.

AWON EBUN ISE- IRANSE
Iwonyi ni awon ebun maraarun ti a daruko ninu iwe Efesu 4:11. A n pe awon ebun wonyi pe o je ebun- ipe ti Jesu Oluwa fi pe iru awon kristiani kan ti o si ya won soto fun akanse ise- iranse ninu ijo- Efesu 4: 11-14. Idi niyen ti a tun se maa n pee ni awon ebun ise- iranse marun (5- fold ministry).

se gbogbo kristiani ni a yonda fun lati ni awon ebun marun wonyi, bee si ni kii se ohun ti eniyan lee fun ara re.

Oruko awon ebun ise- iranse maraarun naa niwonyi:

1. AWON APOSTELI
Awon wonyi ni akanse iko ati iriju ti Olorun pe, ti o yan ti o si ran jade fun akanse ise- iranse ti o nii se pelu fifi ipile otito ihinrere lele ni awon agbegbe titun tabi sisi awon eniyan loju si otito ipile ihinrere ti a ko mo tabi ti a ko ka si tele – 1 Kor 3:9-11.

Iwonyi ni apeere awon Aposteli ninu Bibeli:
v     Awon Aposteli mejila- Lk 6:13-16.
v     Matthias- Acts 1:24-26.
v     Paulu- Gal 1:1
v     Barnaba- Acts 14:14.
v     Androniku ati Junia – Rom 16:7.

2. AWON WOLI 
Awon wonyi ni akanse iranse ti Olorun gbe dide pelu agbara ati akanse ifami- ororo- yan lati je agbenuso fun Oun niwaju awon eniyan-
                        
Ise- iranse woli ju siso asotele nipa isele ojo iwaju nikan lo, o nii se pelu siso okan- Olorun fun awon eniyan, kikilo fun awon apehinda ati kikede iwa- mimo Olorun ati idajo atoke wa lori awon eniyan buburu ti ko ronupiwada- 

Iwonyi ni apeere die ninu awon woli ninu Bibeli:
¨      Elijah-
¨      Elisha
¨      Mika
¨      Jeremiah
¨      Awon woli lati Jerusalem- Acts 11:27-28.
¨      Agabu- Acts 21:10-11.
¨      Juda ati Sila- Acts 15:32. 

3. AWON EFANGELISTI
Awon wonyi ni awon iranse ti Olorun moomo gbe dide pelu akanse agbara ati ifami- ororo- yan lati kede ihinrere opolopo okan sinu ogba- ajara Kristi-

4. AWON OLUSO AGUNTAN
Awon wonyi ni awon iko ti Olorun yan pelu akanse ifami- ororo- yan ati agbara lati bojuto awon aguntan- Olorun ati lati maa mu won dagba sii ninu ore-ofe ati imo Jesu Kristi-

5. AWON OLUKONI
Awon wonyi ni Olorun fi akanse ifami- ororo yan ti o si fun ni ogbon ati imo- ijinle nipa awon ohun ti emi lati fi oro Olorun koni ni ona to lee yeni yeke yeke – Acts 18:25, 2 Tim 1:11.


AWON EBUN ISE- ISIN (Motivational gifts)

Niwon igba ti a ti ri aridaju lati inu eko oro Olorun wipe ko si kristiani kan ti Olorun ko fun ni ebun kan tabi omiran, O wa ku sowo onikaluku lati sawari awon ebun naa ati lati Awon wonyi ni ebun meje ti a daruko ninu iwe Rom 12:3-8. A n pe won ni ebun ise- isin nitori pe o je awon ebun ti Olorun gbin sinu kristiani kookan lati ru won soke fun oniruuru ise- isin ninu ara Kristi (ijo Olorun). Awon ebun wonyi je ifarahan Olorun lati ba aini ijo pade, lati gbe ijo ro ati lati maa mu ijo dagba sii. Ko si kristiani kan ti Olorun ko fi ebun kan tabi ju be e lo fun.

Oruko awon ebun mejeeje naa niwonyi:

ISOTELE: Awon ti a fi ebun yi fun ni Olorun saba maa n lo gege bi “oju” lati ri asiri ibi ti esu tabi ese fara pamo si ninu ijo, lati toka sii ati lati so okan Olorun jade fun awon eniyan re nipa isele atehinwa, isele isinsinyi tabi ti ojo iwaju.

Olorun maa n lo ebun isotele lati mu ese awon ayanfe duro ninu ijo, lati gbawon niyanju ati lati tu won ninu ni – 1 Kor 14:3.

ISE- IRANSE    
Awon kristiani to ni ebun ise- iranse (iranlowo) ni Olorun saba maa n lo lati se akanse iranlowo tabi ise- iranse fun awon ayanfe fun idagbasoke ijo Olorun – Lk 22:24-27. Awon to ni ebun yi lee se ise- isin won ninu ijo Olorun nipase orin- ihinrere, ere ori itage (drama), asona (usher) olutoju ayika ati sise ise- isin fun awon bii opo, alaini, omo orukan ninu ijo abbl.

OLUKONI- Awon wonyi ni Olorun fun ni imo ati ogbon lati maa wadi ijinle otito eko oro Olorun ati lati maa fi ko awon ijo fun ifese mule won ninu Kristi.

Iru won lee je oluko ile- eko ojo isinmi, oluko eko Bibeli (Bible study teachers), oluko ile iwe Bibeli, oluko awon ewe abbl.

IGBANINIYANJU- Awon wonyi ni kristiani ti Olorun fun ni ebun igbaninimoran (counselling) lati maa to awon ayanfe sona ati lati maa mu won lokan le lasiko iponju.

IFIFUNNI- Awon wonyi ni kristiani to ni ebun ififunni lati maa fi owo atawon ohun ini won se iranlowo ati atilehin fun ijo Olorun, awon iranse Olorun ati awon ara ninu Oluwa.

OLORI- Awon kristiani wonyi ni a fun ni ore- ofe lati lee se akoso ijo (church administration) tabi awon elegbejegbe ninu ijo (olori egbe obinrin rere, okunrin rere, abbl).

AANU- Awon wonyi ni Olorun saba maa n lo ninu ijo lati sakiyesi awon to ni isoro, iponju tabi aini kan ati lati se agbateru bi isoro naa yoo se di yiyanju.

Won saba maa n se aanu ati iranlowo fun awon alaini, awon opo, alaisan abbl ninu ijo Olorun.

AKIYESI PATAKI
A gbodo sakiyesi wipe gbogbo awon ebun wonyi lo n sise papo ni ifowosowopo gege bi oniruuru eya ninu ara kan soso lai si iyapa tabi adase- 1 Kor 12:12-31.

BI O SE LEE SAWARI ATI BI O SE LEE SAMULO AWON EBUN EMI RE


samulo won lekun rere.

Iwonyi ni awon igbese ti a lee gbe:
1. Ya ara re si mimo fun Olorun, ki o si fi ara re jin fun sise ife Re- 2 Tim 2:19-21.

2. Mura lati fi tokan tokan sin labe adari ati lati sise takuntakun fun ilosiwaju, ise-rere ati anfani awon elomiran lai wa ere tabi iyin eniyan- Deut 34:9, 2 Oba 3:11, 2 Tim 1:6.

3. Maa kiyesi ara re- 
- Kini awon nkan ti o je ipongbe okan re, ohun to maa n wu o lati se tabi ohun ti o n ni irusoke lati dawole?
- Kini idi ti awon nkan naa se n wu o lati maa se? Bi o ba je nitori ife- owo, ilepa fun ipo, okiki, ominira lati te ife eran ara lorun, iyin eniyan tabi iru awon nkan miran ti o yato si mimu ogo ba oruko Kristi ati idagbasoke fun ijo Olorun; sora etan esu ni – Acts 8:17-23.
- Nje awon nkan naa ro e lorun lati maa se ati wipe se o n mu eso jade?
- Kini ijerisi awon eniyan (awon adari ati ara ninu Oluwa) nipa awon nkan naa nigba ti o ba n se won?

4. Bere si nii fi otito inu lo awon ebun re nibi ti o wa, ki o ma si se kegan ibere kekere – Lk 16:10, Matt 25:21.

5. Maa fi emi irele ati okan- tutu gba itoni, ikoni ati ibawi awon adari lori lilo awon ebun re – Gal 2:1-2.

6. Mase kegan tabi se ilara eni to ti n samulo ebun tire lona to tayo ju tire lo. Sugbon re ara re sile ki o si fara bale kekolara won pelu inu rere- Heb 6:12, 13:7. (iwe, Cd etc)

7. Maa jowu ohun rere, ki o si maa lepa lati tele apeere awon to ti ni idagbasoke ju o lo.
Sugbon ma se sojukokoro si ebun elomiran tabi kegan ebun re- Rom 11:13.

8. Mase so ara re di orogun tabi ba enikeni se ifigagbaga aito nipa lilo awon ebun re. Sugbon maa se ohun gbogbo fun ijere okan, igbero awon ara ninu Oluwa ati idagbasoke ijo Kristi pelu inu kan ati okan mimo- 1 Peter 4:10.

9. Sora fun emi oroju, imele, tabi iwa ole to maa n mu ki eniyan sun ojuse oni si ola- Oniwasu 11:4-6, Rom 12:11.

10. Sora fun emi iberu ati iyemeji. Maa lo awon ebun re lore koore pelu emi igboya ati igbagbo- 2 Tim.1:6-8. Bi o ba se n lo ebun re si ni yio maa po si ti yio si maa dagba sii. Nitori naa, maa fi gbogbo igba ati akoko re lo awon ebun naa.

11. Mase gba ki esu ya ebun re lo lati se lodi si eto Olorun, ife Olorun tabi oro Olorun ninu aye enikeni tabi ninu ijo Olorun- James 3:13-18.

12. Sora fun lilo ebun-emi pelu okan arekereke lati mu ifekufe ti ara re se- 2 Sam 15:1-13.

Thursday, 11 September 2014

YOU CAN ALSO LEARN FROM THIS!



                  
An Open Letter by a Pastor to a Pastor
I have always felt compelled to do some write-ups on the family (which really is a very broad subject).
Incidentally, an open letter by Emeka Asinugo, a London-based journalist to Pastor Chris Oyakhilome’s wife did a fine piece of work in addressing some of the areas I felt needs addressing.

In case there is someone out there who is not aware, Pastor Chris Oyakhilome is the founder and president of the Believers' Love World Inc (popularly known as Christ Embassy). The sad news however, is that Pastor Christ's wife, Anita, who is also the church's vice president has filed for divorce on grounds of adultery and unreasonable behaviour - although this allegation of adultery has been denied by the pastor. Needless to say, this whole divorce scandal is fast causing chaos and also dividing the Christ Embassy church.

It should however, be borne in mind that we are not trying to celebrate this crisis; neither are we trying to exaggerate or exacerbate it in anyway. It is indeed our fervent prayers that the dear good Lord will restore peace, not only in that home, but also in the ministry.

Meanwhile, I will like to share with you Emeka Asinugo's open letter to Anita, Pastor Chris' wife. I think the letter is timely and clearly instructive too. Please feel free to give your comments afterwards.   

Our dear Anita,
I am addressing this letter to you because I know that it is you who will hold the key to triumph over the challenges that have recently raised their ugly heads in your family and in your ministry. I am convinced that even if you don’t read this letter directly from me, some of the numerous members of Christ Embassy across the globe could read it and draw your attention to the words of an old man who is pretty much in the same calling as you and your husband are. I am writing this from my home: The Vicarage, St. Matthew’s Church of England, Stratford, E15 4JX, where my wife, Christy is the Vicar, and the co-ordinating Chaplain of Westfield, Stratford City.

We were all taken aback when we read about your intention to file for a divorce against your husband, Pastor Chris. It was a scandal, Anita, and you must not let it happen.
I need not tell you that in today’s world, many factors tend to get in the way of successful marriages. It is, therefore, practically impossible to recommend a general panacea for all the troubles that can hamper the success of any marriage. But in all our travails, as Christians, we must bear in mind the fact that in a very profound sense, marriage is the most intimate of human relationships, involving sharing a person’s entire life with his or her spouse. By its very nature which emphasizes conjugal love, the institution of marriage is ordained for procreation and for the ultimate education of children who come from such marriages. It calls for self-surrender to the other spouse, a surrender that is so intimate and complete that spouses become “one,” not only in body, but also in soul, without necessarily losing their individual identities.

As the servants of God, you must ask yourselves where the ultimate education of your children comes into this divorce prompting. If this divorce actually takes place, how would your daughters who you are preparing to become future leaders in the church and mothers in the family feel, knowing they come from a broken home? And how do your numerous followers interpret your individual identity with reference to your commitment to family and church?

There is an African adage that says: there is no age when a man can say: ‘I have known it all’. That adage also applies to the institution of marriage. No one can claim to know all there is in that human relationship called marriage. It is a university. Those in it learn by the day from it. And most times, the lessons come in different shapes, culminating in various experiences. As a result, the marital experiences of people actually differ one from another, depending on circumstances and such factors as upbringing, environmental pressure and work demands.

In all of these, no one can claim to have a ready answer to all the myriads of problems that couples face daily in their marriage relationships. It is even more complicated these days when people marry for various reasons that can range from legal, social, emotional and economic needs to spiritual stability or upliftment. But no matter the reason a couple gets married in the first place, the demands of marriage remain ultimate and constant. Husband and wife must have a unity of purpose in all their undertakings. In short, they must be seen as, and remain, “an item” in the eyes of their society.

Many of your admirers across the globe want to believe that work pressure, which is pressure from those you work with or think you are working with, is responsible for this undesirable development of you, Anita, filing for a divorce against Chris. The truth they want to believe is that not only has Satan attended service at Christ Embassy, just as he attends services in all churches that are reputed to be doing well, he is waiting to receive Holy Communion! He has penetrated your ministry and is using your work force to direct you. That is the challenge.

Don’t forget that God allowed Satan to sift the quality of those who profess to worship Him. God cannot be mocked. If Satan wins this battle, then God was never in your Ministry in the first place. Your millions of admirers across the globe will be greatly disappointed but they will not make any mistake about the truth.

You sure must know that your admirers, even from other Christian denominations are in their millions. Many of them look up to you as their role model. Think again. Must you let them down? Is this idea of divorcing Chris so binding? Think about it again. Is this not selfishness? Here in England, many homes break up, with their families torn apart. But when you look at the situation closely, you find that selfishness on the part of one of the spouses was the fundamental reason the family broke up. Should that be the testimony of your Ministry? Would you allow material things like money or alleged sexual indulgence destroy your Ministry and make a mockery of all you have invested into it? To remain married, spouses must be ready for a long-term commitment in every conceivable respect, financially, emotionally and in terms of maturity and ageing.


Having said this much, I would like to quickly point out that there are many things about marriages, especially among Christian Families that are often taken for granted. One of them is the sacrosanct promise publicly recited by couples in front of their witnesses, and in front of God. They usually vow to love, cherish and respect each other “until death do us part!” Think about the admonition God gave Adam in the Holy Book. Adam and his wife Eve were the first recorded couple on earth, according to our Christian belief. God created the Garden of Eden for them, with all the glamour and beauty that the scenic environment portrayed, just as He has prospered Christ Embassy. The Holy Book mentions that husband and wife explored the Garden naked. They were not ashamed of their nakedness. They must have been as innocent as a newly born child. That was how God wanted them to be – innocent. God specifically told Adam not to eat of the forbidden fruit in the centre of the Garden of Eden. God told him: “Of every tree of the garden you may freely eat; but of the tree of the knowledge of good and evil you shall not eat; for in the day that you eat of it, you shall surely die.”

The serpent, described in the Holy Book as “more cunning than any beast of the field that the Lord had made” prevailed on Eve and she convinced her husband to disobey God and eat of the forbidden fruit. But Adam lived for many more years before his physical demise. It means that God was not talking about the physical death of Adam. God meant that Adam would die spiritually. Adam’s spiritual death was not interpreted at the time God told him he would die if he ate of the tree of the knowledge of good and evil. No one knew the mind of God when He spoke to Adam about the tree. But God’s decree happened. The spiritual death of Adam and his wife ushered sin and death into the world. For disobeying God, Adam died spiritually and his death distanced him and his wife from God.

By the same token, modern marriages can die spiritually. When husband and wife fail to upkeep their vow to cherish, love and respect each other; when selfishness and the desire to be the one left standing at the end of the day is inadvertently at the centre of their relationship; when the ill-conceived advice of “frienemies” (half friends and half enemies) holds sway in their marriage, that union is doomed to spiritual death. The couple will be separated from each other, just as Adam was separated from God. The couple may still be living together as Adam and Eve continued to live in the Garden of Eden. But in the spirit, they have been disconnected from God who brought them together initially.

Yes. Even the Elders and Pastors of Christ Embassy are not free from all this. They too have a case to answer. No Christian marriage can simply crash without series of warnings. And we make haste to ask: where were the Elders and other Pastors of Christ Embassy when this entire trouble started? Where were they when it continued and when it was allowed to escalate to this world-wide level? Where were they? What did they observe? What was revealed to them, even in their prayers? And what did they do to salvage the ugly incident that was coming on to daint the image of Christ Embassy?

Anita and Chris, you must surely know that the devil is at work in your Ministry. You must not let this happen. Millions of your admirers out there will be very disappointed. Don’t listen to those frienemies of yours who are pretending to advise you genuinely, because they are not. You are beautiful, Anita. Chris is handsome. And I am sure this combination of beauty and brain is what has attracted so many people to you and to your ministry. Call Chris to prayer over this challenge, and withdraw the suit from court. That is what all your admirers feel you should do. Don’t allow money or things of the flesh to come between you and the love of God expressed in you as a great woman of God.

Pastor Benny Hinn had this temptation. The devil set a booby trap for him. His family was tearing apart. But he overcame the gripping power of the Evil One. He triumphed. And today that testimony stands strong in his favour and profile. The world is watching, hoping that you prove who you really have been. Your children are waiting, not to be stigmatised with the label of children who came from a broken home. Christians all over the world are praying that as a great woman of God, God Himself will reveal the future of this divorce road you appear to have followed to you, Anita. And we all believe that you will triumph over this period and live to give testimony of God’s goodness in your life. Paul is advising you in Ephesians 6:10 to be “strong in the Lord and in His mighty power. Put on the full amour of God, so that you can take your stand against the devil’s schemes. For our struggles are not against flesh and blood, but against the rulers, against the authorities, against the powers of this dark world and against spiritual forces of evil in heavenly realms. Therefore, put on the full armour of God, so that when the day of evil comes, you will be able to stand your ground.”

Paul himself summarises this challenge that seems to be rocking your family and ministry in 2 Corinthians 6: 3-10: “We put no stumbling block in anyone’s path, so that your ministry will not be discredited. Rather as servants of God we commend ourselves in every way: in great endurance, in troubles, hardships and distresses; in beatings, imprisonments and riots; in hard work, sleepless nights and hunger; in purity, understanding, patience and kindness; in the Holy Spirit and in sincere love; in truthful speech and the power of God; with weapons of righteousness in the right hand and in the left; through glory and dishonour, bad report and good report; genuine, yet regarded as impostors; known, yet regarded as unknown; dying, and yet we live on; beaten, and yet not killed; sorrowful, yet always rejoicing; poor, yet making many rich; having nothing, yet possessing everything.”

More to come on family focus. Meanwhile, your comments on todays's edition will be highly appreciated.

Shalom!

Wednesday, 3 September 2014

Do you agree that Kim K and Beyonce have revolutionized our generation’s view of what beautiful is?



Do you agree that Kim K and Beyonce have revolutionized our generation’s view of what beautiful is?



Is this what beauty really is? Please drop your comments and lets' learn together.

 

Thursday, 21 August 2014

What manner of fruit have you eaten?



What manner of fruit have you eaten?

Fruits are the sweet and fleshly product of a tree or other plants that contain seed and can be eaten as food.
They are also important source of vitamins and carbohydrates like fiber and sugar. Fruits are ordinarily meant to add nutrients and also to nourish our health for proper functioning, to build our immune system against infections and diseases, to repair our body tissues and to improve our overall well being.

For the sake of your soul which happens to be the most important to GOD, I will want to share this divine inspiration on the implication of the fruit of the knowledge of good and evil that Adam and Eve ate in the Garden of Eden at the beginning of human existence. Sincerely, I don’t intend telling a story but I want to point us to the saying of Jesus Christ which I sense is very related and indeed a restoration, instruction and command to live above the carnality we inherited from Adam and Eve base on the” knowledge” and the eye opening they suddenly garnered due to the forbidden fruit that they ate.


I will like to declare the words of Jesus in Matthew 18:2-3 “JESUS CALLED A LITTLE CHILD TO HIM AND PUT THE CHILD AMONG THEM, THEN HE SAID, “I TELL YOU THE TRUTH, UNLESS YOU TURN FROM YOUR SINS AND BECOME LIKE LITTLE CHILDREN, YOU WILL NEVER GET INTO THE KINGDOM OF HEAVEN”
Adam and his dear wife never felt ashamed of their nakedness until they ate the forbidden fruit, they were not “sensible enough” to know that they needed to hide from God, they were not wise enough to know how to meet themselves to bear children, they were not as wise, knowing how to till the ground. I wonder how they knew that leaf from a tree could cover their nakedness and many more things they suddenly became a genius about even when they had not been taught by anyone.

You can imagine your life today, you seldom knows all that is good for you  “even beyond what God knows about us”… none of us wants to fall short of men’s standard and praise, none of us like to be embarrassed or face any shame even if it be for Christ. We have all become professors knowing what is best and good for us, what normally should not cause us shame has become a matter to cover, because of this we are all running a rat race to pursue vanity and frivolities.

In the days of Adam he had no ambition other than to tend the garden God has given him, he was so childish in heart that all he cared about was to flourish and enjoy the pleasure of where God has placed him… In our own days we know the wife that is good for us, we rub after fashion more than God, everyone has turned to men’s pleasers rather than the pleaser of God, the work of God is of no great importance to us than our own ambitions and personal visions…. Agape love seems to be far from us and sex has become one of the major reasons that we all wants to marry, we are not even sincere as to face God with our nakedness, we cover up before men and also before God. Everyone has almost become a hypocrite.

To conclude this piece, please let us reconsider the exhortation of JESUS CHRIST; becoming a child again, assuming to know nothing, presenting yourself as an infant without understanding, but trusting the lord on all areas of our life, this remains the only way to go far in our walk with the Lord and to find real fulfillment and accomplishment.

Wednesday, 13 August 2014

Always Aim Higher

Always Aim Higher
Having an aim or ambition is one good quality anyone could and should possess. It simply implies that you have a set goal(s) or objective(s) which you want to achieve in a particular way, at a particular pace possibly and at a set time. Being ambitious also involves having a set mission (short term goals) and vision (long term goals) and probably mapping them down.
Our main concern here however, is on how not to just aim, but to always aim higher. But then, you must first discover or know what you want. Then aim for it. Pay little or no attention to side attractions. Aiming higher therefore presupposes thinking and dreaming big; having this big picture . . . this huge mission and vision beyond what you could have otherwise been ordinarily able to achieve without much fuss.

Why aim higher? Firstly, it gives you that extra hunger and drive which in turn propels you to break monopolies, barriers and limitations. It can also push you to breaking existing records thereby setting new ones. An extra drive can make all the difference between a simple success and a very huge success. Secondly, aiming higher is harmless. Thirdly, when the chips are down having aimed higher and things don’t work out exactly as planned, there is still a good chance that the result might still be good. I mean, you may still achieve a considerable amount of (remarkable) success in place of the extremely remarkable success you earlier anticipated. Much like when a student works hard for straight “As” in an ideal educational system. There is a very high likelihood that if he doesn’t make those “As”, the least he might make could be “Bs” or a mixture of both. Reason being that he had already set his mind on the higher picture and vigorously pursued it. And with all the time, efforts prayers and faith he had put in, it so hard imagining him getting anything beyond “Bs". So . . . well, he isn’t able to hit his set target. But then, he still hasn’t failed either; and yes, he still has got some good results too. Got my gist now? Yeah!

There is a caveat though. . . 

Aiming higher requires a surge of higher drives, hunger and zeal. Therefore, if not well tamed could turn to be a hydra-headed monster sapping even the most morally pious or spiritually upright person of his virtues. The adsverse effect could therefore lead to moral decadence or spiritual bankruptcy. Thus, if care is not taken, it could turn out to be the cause of greed, corruption, occultism, robbery, immorality and some other vices and evils as seen in our society today. Being ambitious should not push you to being overambitious.

Importantly also, you should be wary of way-out-of-this-world or unrealistic targets when having a higher aim. Your vision must be very clear to you (even if others do not see any prospect in it). There is no crime in having very difficult or seemingly impossible goals or targets so long they are realistic. That way, won’t end up building your castle in the air. You also overcome the error of conceiving mere fantasies instead of dreams; or the near impossible task of searching for shadows to chase even in the dark. I bet your time, energy and resources are too precious to be wasted on a wild goose chase. Your plans should therefore be well mathematized and mapped out.

You can generally overcome the temptations that come along with having higher aims by keeping good companies of like minds; reading good books which essentially includes the bible; and of course, the place of prayers can never be overemphasized!
So friends, I figure its time enough you took a go at it. Always aim higher. Stay positive and stay focused. We never can tell, you can turn out to be the next Dangote or even Bill Gate. These are no aliens, but human beings with humble beginnings like most of us. Isn’t it? Remember, the best is yet to be born just as the beautiful ones are not yet born.
Clearly, the earnest expectation of creation eagerly awaits your manifestation (Romans 8: 19).
Shalom!

Thursday, 7 August 2014

CHRISTIAN PERSECUTION IN OUR DAYS

Christian persecution


The Bible clearly teaches that society will degenerate in the end times, becoming as evil as it was in the days of Noah (Matt. 24:37-39). The Apostle Paul, speaking as a prophet, says that society will descend into a black pit of immorality, violence, and paganism (2 Tim. 3:1-5). He asserts that men will be "lovers of self, lovers of money," and "lovers of pleasure." People will be "boastful, arrogant," and "unholy," and children will be "disobedient to parents."

 Sounds like the evening news, doesn’t it? In short, we have arrived.
Signs of Coming Persecution
We should be deeply concerned over these developments, not only because we are witnessing the destruction of our beloved Country, but because both Jesus and Paul prophesied that when these things occur, the church will come under attack and Christians will be persecuted.

Jesus said that as lawlessness increases, "most people’s love will grow cold" (Matt. 24:12). He stated that many professing Christians will "fall away" and will proceed to cooperate in the persecution of their former brothers and sisters in Christ (Matt. 24:10). Paul indicates the same thing when he says that people will be "haters of good" and that they will therefore be "brutal" and "reckless," reviling those who stand for righteousness (2 Tim. 3:2-5).

 We are watching these prophecies come true today before our very eyes, both here in Nigeria and around the world. As our culture has secularized and paganized, Christianity, the church and Christians have come under increasing attack as "intolerant bigots." The attacks are going to intensify, and it will become increasingly difficult for Christians to stand for righteousness. Jobs will be lost. Careers will be destroyed. Christians will even be sent to prison for speaking out against evils like homosexuality, gay marriage, because such pronouncements will be labeled as "hate crimes."

What then are those of us who love Jesus to do as we face a rising wave of ridicule, harassment, and persecution for our faith? How shall we live for Christ in the end times? Let me suggest a few guidelines.Watch-out for the second edition of this publication

Wednesday, 6 August 2014

You No Longer Have Time For God Because...


Satan called a worldwide convention of demons.

In his opening address he said,

"We can't keep Christians from going to church."

"We can't keep them from reading their Bibles and knowing the truth."

"We can't even keep them from forming an intimate relationship with their saviour."

"Once they gain that connection with Jesus, our power over them is broken."

"So let them go to their churches; let them have their covered dish dinners, BUT steal their time, so they don't have time to develop a relationship with Jesus Christ.."

"This is what I want you to do," said the devil:

"Distract them from gaining hold of their Saviour and maintaining that vital connection throughout their day!"

"How shall we do this?" his demons shouted.

"Keep them busy in the non-essentials of life and invent innumerable schemes to occupy their minds," he answered.

"Tempt them to spend, spend, spend, and borrow, borrow, borrow."

"Persuade the wives to go to work for long hours and the husbands to work 6-7 days each week, 10-12 hours a day, so they can afford their empty lifestyles."

"Keep them from spending time with their children."

"As their families fragment, soon, their homes will offer no escape from the pressures of work!"

"Over-stimulate their minds so that they cannot hear that still, small voice."

"Entice them to play the radio or CD player whenever they drive." To keep the TV, VCR, CDs, ipad and their PCs going constantly in their home and see to it that every store and restaurant in the world plays non-biblical music constantly."

"This will jam their minds and break that union with Christ."

"Fill the coffee tables with magazines and newspapers."

"Pound their minds with the news 24 hours a day."

"Invade their driving moments with billboards."

"Flood their mailboxes with junk mail, mail order catalogs, sweepstakes, and every kind of newsletter and promotional offering free products, services and false hopes.."

"Keep skinny, beautiful models on the magazines and TV so their husbands will believe that outward beauty is what's important, and they'll become dissatisfied with their wives. "

"Keep the wives too tired to love their husbands at night."

"Give them headaches too!"

"If they don't give their husbands the love they need, they will begin to look elsewhere."

"That will fragment their families quickly!"

"Give them Santa Claus to distract them from teaching their children the real meaning of Christmas."

"Give them an Easter bunny so they won't talk about his resurrection and power over sin and death."

"Even in their recreation, let them be excessive."

"Have them return from their recreation exhausted."

"Keep them too busy to go out in nature and reflect on God's creation. Send them to amusement parks, sporting events, plays, concerts, and movies instead."

"Keep them busy, busy, busy!"

"And when they meet for spiritual fellowship, involve them in gossip and small talk so that they leave with troubled consciences."

"Crowd their lives with so many good causes they have no time to seek power from Jesus."

"Soon they will be working in their own strength, sacrificing their health and family for the good of the cause."

"It will work!"

"It will work!"

It was quite a plan!

The demons went eagerly to their assignments causing Christians everywhere to get busier and more rushed, going here and there.

Having little time for their God or their families and friends.

Having no time to tell others about the power of Jesus to change lives.

I guess the question is, has the devil been successful in his schemes?

You be the judge!!!!!